Gomina ana ipinlẹ Oyo, Otunba Christopher Adebayo Alao-Akala ti kede pe oun ko ni dije fun ipo gomina ipinlẹ naa mọ nibi ti oun ba a de bayii. Otunba Akala sọrọ yii lori eto kan to waye ni ileeṣẹ ...
Gbajugbaja olorin Fuji ti o tun jẹ ọmọ ilẹ Ibadan, Alhaji Taye Adebisi ti ọpọ eeyan mọ si "Taye Currency" ti ṣe alaye bi Gomina tẹlẹri n'ipinlẹ Ọyọ, oloogbe Christopher Alao-Akala ṣe mu ki oun lu ...
Some results have been hidden because they may be inaccessible to you
Show inaccessible results